Saudi Arabia Àtí Iran Tún Ìbáṣepọ̀ Wọ́n Só dọin-dọin
Iran àti Saudi Arabia gbà ní ọjọ́ Ẹtì látí tún àwọn ìbáṣepọ̀ wọ́n ṣé lẹ́yìn ọdún méje.
Àdéhùn náà wáyé lẹyìn ọjọ́ mẹ́rin tí ìjíròrò tí kọ́ wáyé ní Ìlú Beijing láàrín àwọn òṣìṣẹ́ ààbò Orílẹ̀-èdè méjèèjì.
Gẹ́gẹ́ bí àlàyé ìbáṣepọ̀ náà…