Ààrẹ Buhari Bú Ẹnu Àtẹ́ Lú Ìpànìyàn Ọmọ Ẹgbẹ́ Òṣèlú Labour Party
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari tí bú ẹnu àtẹ́ lú ipaniyan burúkú tí wọ́n pá Oyibo Chukwu, ẹní tó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party ní Enugu East Senatorial District àti olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ ní Gúúsù Ìlà Oòrùn Nàìjíríà.
Ààrẹ náà…