NAFDAC Ṣèlérí Látí Ṣé Àbójútó Òògùn Ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Àjọ tí orílẹ̀-èdè fún Oúnjẹ àti Oògùn fún àbójútó àti ìṣàkóso (NAFDAC) sọ pé àwọn kó ní sinmi lórí ìṣẹ́ rẹ̀, nínú ìgbìyànjú rẹ̀ láti ṣàkóso lílo òògùn ní Nàìjíríà
Olùdarí àgbà tí ilé-iṣẹ́ náà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Mojisola Adeyeye, ṣé ìkéde…