Orílẹ̀-èdè Philippine Bẹ̀rẹ̀ Ìdìbò Yan Ààrẹ tuntun
Orílẹ̀-èdè Philippine bẹ̀rẹ̀ ìdìbò láti yan Ààrẹ tutun ní ọjọ́ ajé àti ẹgbàásán
òṣìṣẹ́ mìíràn láti gbogbo àwọn ìpele ìjọba.
Awọn oludije ti wọn yoo yan ni igbakeji aarẹ,awọn aṣofin mejila, awọn ọmọ ẹgbẹ …