Opera sún sẹ́gbẹ̀ẹ́ fún ìdíje Nigerian Idols
Ìgbésáfẹ́fẹ́ Nigerian Idols tó wáyé lọ́jọ́ kẹrìnlélógún, oṣù kẹrin, ọdún 2022 ya àwon olólùfé David Operah lẹ́nu bí ó ṣe já kúrò nínú ìdíje náà.
Ni Ibẹrẹ iṣafihan naa,awọn oludije n ṣiyemeji nigba ti wọn pe…