Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

NLC/TUC

Ìjọba Nàìjíríà Tún Ṣé Ìdánilójú Ìbọwọ̀ Sí Àdéhùn Wọ́n Pẹ̀lú Ẹ̀gbẹ́ Òṣìṣẹ́

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ Ẹtì tí fí dá àwọn ẹ̀gbẹ́ òṣìṣẹ́ lójú látí bọ̀wọ̀ fún àdéhùn tí wọ́n fọwọ́sí pẹ̀lú ẹ̀gbẹ́ òṣìṣẹ́ (NLC/TUC). Gẹ́gẹ́bí Mínísítà tí Ìpínlẹ̀ fún Iṣẹ́, Ìyááfín Nkeiruka Onyejeocha, ìjọba kó ní ìrẹ̀wẹ̀sì nínú…

Ìjọba Nàìjíríà Rọ́ Àwọn Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ Láti Bọ̀wọ̀ Fún Àṣẹ Ilé-ẹjọ́

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ké sí àwọn àjọ òṣìṣẹ́ láti má ṣe gúnlé yanṣẹlodi, kí wọ́n bọ̀wọ̀ fún àṣẹ tí Ilé Ẹjọ́ pá wọ́n ọjọ́ karún-ùn oṣù kẹfà. Ilé-ẹjọ́ tí pàṣẹ fún Ìgbìmọ̀ àwọn Òṣìṣẹ́ (NLC) àtí (TUC) láti má gúnlè iyanṣẹlodi latari…
button