Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

#nigeriabettertogether

Ọ̀RỌ̀ ÀÀRẸ TINUBU LÓNÌÍ ỌJỌ́ AYẸYẸ ÀYÁJỌ́ ỌDÚN ÒMÌNIRA LÓRÍLẸ̀DÈ NÀÍJÍRÍÀ

Ẹ̀yin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà, Pẹ̀lú ìdùnnú ọkàn ní mo fi n ba yin sọrọ lónìí ọjọ́ kinni, oṣu kẹwàá, Ọdun 2023, Ọjọ́ ayẹyẹ ọdún òmìnira ti Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà pé Ọdún Mẹ́tàlélọ́gọ́ta gẹ́gẹ́ bíi  Ààrẹ…

Ọ̀RỌ̀ ÀÀRẸ BOLA TINUBU: ÀYÍPADÀ TUNTUN TI DÉ BÁ ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ

Ẹ̀yin ènìyàn mi lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Mo dúró sí wájú yin lónìí, Ọjọ́ Kọkàndínlọ́gbọ̀n, Ọṣụ̀ Karùn-ún, Ọdún 2023 láti tẹ́wọ́ gba iṣẹ́ tí ẹ fi rán mi. Ìfẹ́ tí mọ ní sí orílẹ̀-èdè yìí dúró digbí. Ìgbàgbọ́ mìi nínú yín ṣi…

Ètò Ìbúra Fún Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Àti Ìgbákejì Rẹ: Ìlọsíwájú Yín Ni Yóò Jẹ Mí Lógún – Makinde

Ètò ibura fún Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti ṣe àkóso Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ fún sáà ẹlẹẹkeji ló wáyé ni pápá iṣere Obafemi Awolowo ti a mọ sí (Liberty Stadium) to kalẹ sí àgbègbè Òkè -Ado ni ìlú Ìbàdàn tíì ṣe olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni Ẹkùn Gúsù Iwọ Oòrùn…

Wọ́n búra fún Kashim Shettima gẹ́gẹ́ bí igbákejì ààrẹ Nàìjíríà

Wọ́n ti búra fún Kashim Shettima gẹ́gẹ́ bí igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n,2023. Àwọn  ènìyàn pàtàkì nílé àti látòkèèrè,adari Adúláwọ̀ àti àwọn adarí Nàìjíríà tẹ́lẹ̀…

ÈTÒ ÌFINISÍPÒ: Omi tuntun yóò rú lónìí bí Ìpínlẹ̀ Méjìdínlọ́gbọ̀n yóò Ṣe bú́ra fún…

Lẹ́yìn àṣeyorí ìdìbò Gbogbogbòo ní orílẹ̀-ẹ̀dè Nàíjíríà, àwọn Ìpínlẹ̀ méjìdínlọ́gbọ̀n yóò búra fún Ijọba tuntun lónìí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2023. Awọn ipinlẹ mejidinlọgbọn ti yoo ṣe ibura lónìí ni, Ipinle…

Ojú Mì Ni Yó Ṣe- Àwọn ọmọ orílẹ̀-ẹ̀dè Nàíjíríà ti Péjú-Pésẹ̀ Sí Eagle Square Fún…

Awọn ọmọ orílẹ̀-ẹ̀dè Nàíjíríà ti ń dé sí Eagle Square nílùú Abuja fún ayẹyẹ ìfinisípò Ààrẹ tuntun, Asiwaju Bola Tinubu àti Igbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ni kutukutu aago mẹfa aarọ  Òjò to rọ láàárọ̀ yii…
button