Ìlera: Nàìjíríà Yóò Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ètò Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Àwùjọ Ìwádìí
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nípasẹ̀ National Primary Health-Care Development Agency (NPHCDA) tí ṣètò láti ṣé ìfilọ́lẹ̀ Àwùjọ Ìwádìí Innovative-Training and Services Program (CRISP) ni Ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kejilelogun Oṣù Kàrún ùn, Ọdún 2023 ní…