Ikọ̀ ọmọ ogun Nàíjíríà fẹ̀yìn ọlọ̀tẹ̀ Abu Mussab Al-Barnawi balẹ̀
Oluranlọwọ aarẹ lori eto aabo lorile ede Naijria, Babagana Monguno ti gbosuba fu ikọ ọmọ ogun orile ede Naijria fun gudu gudu meje yaya mẹfa ti wọn se lati fẹyin olori ikọ̀ ọlọtẹ to n da ilẹ Afirika laamu iyẹn Abu Mussab Al-Barnawi …