Áfíríkà Kí Ifè Ẹ̀yẹ Àgbáyé Káàbọ̀
Bó tí kú oṣù díẹ̀ tí ìdíje àgbáyé àwọn ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù yóò fí wáyé ní orílẹ̀-ẹ̀dẹ̀ Amẹ́ríkà, Áfíríkà gbàlejò ifè túntún náà.
Ẹgbẹ́ agbabọọlu méjìlélọ́gbọ̀n 32 ní yóó kópa nínú ìdíje túntún náà níbí tí ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù mẹ́rin yóò tí…