Macron, Le Pen gbégbá orókè nínú ìpele kìnní ìdìbò ààrẹ orílẹ̀-èdè Faransé
Ààrẹ Faransé lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, Emmanuel Macron àti ẹnìkejì rẹ̀, Marine Le Pen ni àwọn olùdarí méjì tí ó gbégbá orókè níbi ìpele àkọ́kọ́ ìdìbò Ààrẹ ọdún 2022.
Gẹgẹ bi esi idibo alakọkọ ti o waye ni ọjọ…