Ìpínlẹ̀ Èkó Kìlọ Fún Àwọn Òntájà Lóju Òpópó-ọnà Ojú-Ìrìn Láti Kúró Pátápátá
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó, Ìwọ̀ òòrun guusù orílẹ̀-èdè Náìjíríà, ní ọjọ́ Áìkú, fún àwọn olúgbé àti ontájà òpópónà ojú-ìrìn Èkó sí Badagry wọ́nyí ní ọjọ́ méje láti kúró pátápátá tábi páda sẹ́yìn.
Òpópónà Lagos-Badagry naa ni ojuna ọkọ oju-irin…