Jíjẹ mimú lọ́pọ̀ janturu fún ìṣínu ààwẹ̀
Àwọn Mùsùlùmí ní orílẹ̀-èdè Ígípítì ti péjọ lẹ́bàá tábílìì tí ó gùn san an nan lópòópónà láti ṣínu ààwẹ̀ wọn lápapọ̀ pẹ̀lú oúnjẹ “Iftar”lóríṣiríṣi lọ́pọ̀lọpọ̀, ní agbègbè Matariya, ní ariwá…