Ìrọ̀rùn dé bá gbígba ìwé irinnà sí orílẹ̀-èdè UK
Ìjọba àpapọ̀ ní ọjọ́ ìṣẹ́gun tún fìdí ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ láti mú ìlànà àti gba ìwé ìrìnnà fún àwọn ọmọ Nàìjíríà nílé àti lókè òkun dìrọ̀rùn , bí ó ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ àtúnṣe ìwé ìrìnnà tuntun náà.…