Ilé-iṣẹ́ ológun Nàìjíríà fún Àwọn ẹgbẹ̀rin olùgbé Sókótó ní ìtọ́jú ọ̀fẹ́
Ilé-iṣẹ́ ọmọ ogun Nàìjíríà ikọ̀ kẹjọ ti fún àwọn ènìyàn tí ó ju ẹgbẹ̀rin lọ ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Sifawa, Bodinga ati Denge-Shuni ní Ìpínlẹ̀ Sókótó ní ìtọ́jú ọ̀fẹ́.
Nigba ti o n sọrọ nibi ayẹyẹ naa,…