Ìlera ará ìlú pàápàá jùlọ,ìgbèríko jẹ wá lógún
Ìjọba Zamfara ní ọjọ́ Àìkú, ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ Ìtọ́jú Ìlera abélé, PHC tuntun mẹ́tàlé-lógójì, tí ó sì tún ń pín àwọn ọkọ̀ tí wọ́n fi ń gbé àwọn aláárẹ̀ mẹ́tàdín-láàdọ́jọ láti ṣe àlékún wíwà…