Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

Igbákejì ààrẹ

Igbákejì ààrẹ ,Yẹmí Òsínbàjò gbóṣùbà káre láí fún ilé-iṣẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ SecureID

Igbákejì ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò, ti gbóríyìn fún  SecureID Limited, tí ójẹ́  olùpìlẹ̀ṣẹ̀ alákọ́kọ́ ìwé pélébé alásọdowó tiwantiwa , fún fífi ìlànà kalẹ̀ fùn àwọn ilé-iṣẹ́ Nàìjíríà míràn láti…

Igbákejì ààrẹ, Osinbajo yóò sojú Nàíjíríà níbi ayẹyẹ àjọ̀dún òmìnira Ọgọ́ta ọdún…

Igbákejì ààrẹ, orílẹ èdè Naijiria , Ọjọgbọn Yẹmi Osinbajo  ni yóò máa sojú orílẹ̀ èdè Nàíjíríà níbi ayẹyẹ àjọ̀dún  Ọgọ́ta ọdún (60 years)  ti orílẹ èdè Sierra Leone gba òmìnira, ní èyí tí yóò wáyé ni…