Ifeto somo bibi din iku awon obinrin ku ni ida ogbon – Amoye
Ẹgbẹ to n risi Ilọsiwaju Eto ifetosomo bibi ni orile -ede Naijiria ti sọ pe eto naa yoo din iku abiyamo ku ni ida ogbon.
Alaga Igbimọ Isakoso Imọ-ẹrọ ẹgbẹ ohun, Dokita Ejike Oji,so eleyi di mimo lakoko ifọrọwanilẹnuwo pẹlu awọn oniroyin…