Gómìnà Kano ṣèpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Tinubu
Gómìnà ipinlẹ Kano, Abba Yusuf, ti ṣèpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Bọla Tinubu ní ilé iṣẹ́ Ààrẹ, Villa, Abuja, olú ìlú Nàìjíríà.
Ipade bonkẹlẹ yii waye lori boya Gomina Yusuf fẹ kuro ninu ẹgbẹ to wa, Nigeria People’s Party (NNPP),…