Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

Federal government of Nigeria

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ọ̀rọ̀ – Ọ̀rọ̀ ìdágbére Láti Ẹnu Ààrẹ Muhammadu Buhari, Ààrẹ Orílẹ̀-Èdè…

Ẹ̀yin ènìyàn mi lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, àti àwọn tó ń gbé káàkiri àgbáyé. Mò ń bá a yín sọ̀rọ lóní, èyi tó jẹ́ iṣẹ́ mi tí ó gbẹ̀yìn gẹ́gẹ́ bi Ààrẹ Ìjọba tiwa-n-tiwa tí a yàn sípò gẹgẹ bi ààrẹ orilẹ-ede…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Pèsè Àwọn Òun Èlò Amàyédẹ́rùn Fún Àwọn olufaragba Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìnà

Ilé-iṣẹ́ Pájáwìri tí Orílẹ̀-èdè (National Emergency Management Agency NEMA) ní Ọjọ́ Ẹtì pèsè àwọn òun èlò amàyédẹ́rùn fún àwọn tó pàdánù àwọn òun ìní wọ́n sì ìṣẹ̀lẹ̀ iná ní àgbègbè Malamawar-Dangoli, Karange àtí Kwalele ní ìjọba ìbílẹ̀…

Àwọn Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Fọwọ́sí Ìdáàbòbò Àwọn Ọmọdé Lórí Ayélujára

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti bú ọwọ́ lú ìwé àṣẹ àti ìlànà ìdáàbòbò àwọn ọmọdé lórí ayélujára lọ́wọ́ àwọn òun èlò ayélujára tó lé ní ipá lórí ayé wọ́n. Ìlànà náà ní wọ́n fọwọ́sí ní Ọjọ́bọ̀ ní ìpàdé tí Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ tí Ìjọba Àpapọ̀ tí…
button