Èǹiyàn ọgọ́rùún mílíọ́nù ti wo àwo Burna Boy báyìí
Awọn eniyan to to ọgọrun miliọnu ti wo awo mẹta ọtọọtọ ti ọmọ orilẹ-ede Naijiria to jẹ amin ẹyẹ Grammy,Burna Boy ṣe gbẹyin,’African Giant’,’Outside’,and ‘Twice as Tall’.
Ogbe ’Outside’ jade ni oṣu kinni odun 2018, Grammy yan ’African…