Manchester United Pàdánù Ìfẹsẹ́wọ́sẹ̀ Wọ́n Pẹ̀lú Tottenham 1-0
James Maddison gbá ayo àkọkọ́ wọlé fún ìkọ Tottenham lẹ́yìn ifarapa rẹ̀ nínú ìdíje English Premier League bí wọ́n ṣé bóri ìkọ Manchester United pẹ̀lú ayo kán sí odò (1-0) ní ìlú London, England.
Èyí ní ìgbà àkọkọ́ tí Tottenham yóò…