Ẹgbẹ́ pè Fún Ìdábòbò Ọmọdé Áfíríkà
Àwọn tí ó níí ṣe pẹ̀lú ìdàgbàsókè ọmọdé, ti rọ àwọn òbí àti àwọn alágbàtọ́ láti tún ṣe ìgbìyànjú láti dáábòbò gbogbo ọmọ Áfíríkà nípa ṣíṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí àwọn ìṣe àṣà tí ó léwu àti àwọn…