Ẹ máá fi ẹ̀tọ́ wa dùnwá
Awọn oṣiṣẹ eto ilera nipinlẹ Abia ni ana fi ẹhonu wọn han latari owo oṣu mejila wọn ti wọn ko san, ti won si n banujẹ wi pe ijọba ipinlẹ naa ti sọ igbimọ naa di ibi ibanujẹ, irora, ati iku.
Awọn oṣiṣẹ Igbimọ iṣakoso ile-iwosan Ipinlẹ…