DRC: Àwọn olùgbé Ṣe Ayẹyẹ Ọjọ́ àjíǹde Krísítì Nínú Ogun
Ní agbègbè Rutshuru, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Krìsítíánì ni inú wọn kò dùn lọ́jọ́ Jimọh ‘good Friday’.
Pelu ayẹyẹ nla ọdun ajinde,awọn ọmọ orilẹ-ede Congo lati iha ila-oorun DRC ko le ṣayẹyẹ naa.
Ẹgbẹ ọlọtẹ M23 ti o ja ogun ni…