Nàìjíríà Tún Ṣé Ìdánilójú Ìdúróṣinṣin Sí Ètò Ẹ̀kọ́ Àwọn Ọmọ-kékeré
Ìjọba Nàìjíríà tí tún ṣé ìdánilójú ìdúróṣinṣin fún ìtọ́jú ẹ̀kọ́ àti ìdàgbàsókè àwọn ọmọ-kékeré (ECCDE) lágbára gẹ́gẹ́ bí ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ tó dára àti ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè.
Mínísítà fún ẹ̀kọ́, Dókítà Tunji Alausa sọ èyí nínú ọ̀rọ̀…