Àwọn tó nííṣe ṣe àyẹ́síi ìgbé ayé àwọn àgbẹ̀
Owó káríayé fún ìdàgbàsókè ètò ọ̀gbìn, IFAD-Ètò ìrànlọ́wọ́ àpapọ̀ iyì fún ìdàgbàsókè, VCDP, ti sọ pé ọdún mẹ́sàn án ti òhun ti wà ní ìpínlẹ̀ Ebonyi, Gúsù iwọ̀ oòrùn Nàìjíríà, ti ran ìgbé ayé…