Àgbájọ ọwọ́ lafí ń sọ̀yà
Láti ṣe ayẹyẹ àyájọ́ ọjọ́ Ibà Àgbáyé ti ọdún yìí lónìí, Godrej Nigeria, àwọn tí wọ́n ń ṣe òògùn apakòkòròo GoodKnight Power Shots ti ń ṣe àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ Ìlera ìjọba àpapọ̀ lábẹ́ẹ Ètò ìgbógun ti…