Ààrẹ Bùhárí pinnu pé òhun yóò pèsè ààbò tó péye
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti mu dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè lójú pé, gbogbo làásìgbò tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ní orílẹ̀-èdè yóò tó di àfìsẹ́yìn téégún ń fisọ.
Gomina Ipinle Zamfara, Bello Matawalle ṣe…