Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Sún Ìdíje Àwọn Ọ̀dọ́ Síwájú

0 283

Ẹlẹ́ẹ̀keje irú rẹ̀, ìdíje ti àwọn ọ̀dọ́-National Youth Games NYG ti orílẹ̀-èdè yìí tó yẹ kí ó wáyé nínú oṣù Kejì ní Ìpínlẹ̀ Delta láti ọjọ́ kẹjọ sí ọjọ́ kejìdínlógún ni wọ́n ti sún síwájú.

 

Wọ́n sún síwájú látàrí ìbò tó ń bọ̀ tí yóò wáyé ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n osù Kejì ọdún yìí gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé àgbà pátápátá fún ìdàgbàsókè ẹ̀ka eré ìdárayá àti ọ̀dọ́ ní orílẹ̀-ẹ̀dẹ̀ yìí, Alhaji Ismaila Abubakar se sọ. Ó sọ síwájú pé ki àwọn ènìyàn máṣe bínú, wọ́n ó kéde ọjọ tuntun fún ìdíje náà lẹyìn ìdìbò.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button