Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Buwọ́ Lu ìwẹ Pẹlú Orílẹ̀-èdè Poland lórí nkàn ọ̀gbìn ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀKÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN By Adegbite Oyebisi On Sep 6, 2022 0 277 Share Nàìjíríà àti Poland ti bọwọ́ lùwé to ní ìtumọ̀ lórí ọ̀rọ̀ ohun ọ̀gbìn Èyí wáyé nígbà tí ààrẹ Poland ṣe ìbẹ̀wò sí aare Buhari ní ìlú ìjọba ni ìlú Abuja. Àwọn orílẹ̀-èdè méjèjì ṣe ìlérí láti ṣe ìrànlọ́wọ́ nípa gbígbé ètò ọrọ ajé lárugẹ. 0 277 Share FacebookTwitterWhatsAppEmailLinkedinTelegram
Leave a Reply