Take a fresh look at your lifestyle.

Ọmọ Ilé igbimọ̀ Gbóríyìn Fún Àwọn Ológun Lórí Ètò Ààbò

364

 

Ọmọ Ilé igbimọ̀ aṣojú sòfin tó kéré jù ti gboriyin fún àwọn akíkanjú ọmọ ologun ti wọn sa gbogbo agbára wọn ti ọ̀pọ̀ sì fi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ kí àlàáfíà leè jọba àti ki mìmì kan máleè mi orílẹ-èdè yìí.

Wọn sọ èyí nibi ọjọ́ ìrántí àwọn ọmọ ológun ọdọọdún ti ọdún 2026. Wọn rọ ijọba àpapọ̀ láti tù ètò ìgbàyè gbádùn wọn ṣe dáradára, wọn tun fi dá wọn lójú pé ètò nípa òfin ni ti ààbò ni wọn yóò ṣe daradara.

Asoju igbimo náà, ọ̀gbẹ́ni Kingsley Chinda tun sọ pé gẹgẹbi àwọn amòfin tó ṣe fọkàn tán tó wúlò, igbimọ ṣèlérí pé
ètò nipa òfin ní ti ààbò ní wọn yóò ṣe daradara nibi àti lọnà tó yẹ.

Èyí yóò mú kí àwọn ológun leè fi dá àwọn ènìyàn loju pé ẹ̀mí àti dukia àwọn ara ilu wà lálàfíà láì séwu.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button