Take a fresh look at your lifestyle.

Ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi Ṣetán Látí Ṣé Àṣepọ̀ Pẹ̀lú Àjọ USAID

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 347

Ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi, Iyaafin Uzoamaka Nwifuru tí ṣé àfihàn ìdùnnú rẹ̀ látí Ṣé àṣepapọ̀ pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ America kàn Fún Ìdàgbàsókè káríayé, USAID ṣé amugba lẹgbẹ Ìpínlẹ̀ náà láti mú ìlọsíwájú tó dára bá àwọn ènìyàn Ebonyi.

Iyaafin Nwifuru ṣé ìfọwọ́sowọ́pọ̀ yìí làkókò ìpàdé ibaraẹnisọrọ pẹ̀lú gbogbo àwọn alabaṣiṣẹpọ USAID ní Ìpínlẹ̀ náà ní ọfiisi rẹ̀ ní Abakaliki Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Ebonyi.

Alákóso ètò iṣẹ́ Ìlera lábẹ́ USAID ní ìpínlẹ̀ Ebonyi, Dókítà Ibiam Azu sọ pé Iyaafin náà fẹ láti dá iṣẹ́ àkànṣe kàn kálẹ̀ èyí tó fá ìfọwọ́sowọ́pọ̀ yìí.

Àwọn tó wà níbí ibaraẹnisọrọ náà ní: Ilé-iṣẹ́ America Fún Ìdàgbàsókè Káríayé USAID- Integrated Health Program IHP, AMURT, USAID- Momentum Project, USAID- FEEDiFUTURE Agric program àtí Nutrition Project láàrín àwọn mìíràn.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button