Take a fresh look at your lifestyle.

Ìyàwó Ààrẹ Gbé Òsùbà O káre Fún Ìpínlẹ̀ Anambra.

152

Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ṣẹ́nítọ̀ Oluremi Tinubu ti gbé Òsùbà o káre fún ìpínlẹ̀ Anambra fún iṣé takuntakun rẹ nípa ètò ọ̀gbìn àti fún ìrètí nlá nipa ohun ọ̀gbìn.

O sọ èyí di mímọ̀ lásìkò tí o ló fún ìpàdé pẹ̀lú ìyàwó àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ kàkàkí ìpínlẹ̀ Nàìjíríà.

Lásìkò ìpàdé náà ni o fi àwòrán hàn, èyí to nise pẹlu ìpínlẹ̀ náà, o wa fi ìpínlẹ̀ náà ṣe àpèjúwe réré fún àwọn ìpínlẹ̀ tókun láti wo awokọṣe wọn.

Ìyàwó Ààrẹ gbóríyìn fún Iyaafin Soludo fún iṣẹ takuntakun rẹ láti rí wí pé gbogbo ènìyàn tí o wa s’ibi ìpàdé náà ni o mu ẹbùn pàtàkì ló sí ilè wọn.

Wọn gbà Eko nípa ètò ọ̀sìn àti ètò ọ̀gbìn.

Comments are closed.

button