Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Anambra Tí Kìlọ Fún Àwọn Tó Ń Kọ́ Ilé-èpò Látí Lodi Sí Titẹ́ Òfin Lójú Mọlé

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 350

Ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra tí kìlọ fún àwọn oníṣòwò èpò bẹntiroolu látí lòdì sí kíkọ́ àwọn Ilé-èpò lọ́nà àìtọ́.

Ìjọba t’ẹnu mọ́ pé àwọn kó ní sàn owó gbà mabinu fún irúfẹ́ ilé-èpò tí wọ́n bá wòó.

Wọ́n ṣé ìkìlọ náà lásìkò ifọrọwerọ láìpẹ́ yíì láàrín aṣáájú ẹgbẹ́ àwọn ọ́lọ́jà èpò rọbi tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (Independent Petroleum Marketers Association of Nigeria IPMAN), àtí Petroleum Dealers Association of Nigeria (PEDAN) pẹ̀lú ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra.

Tún kà nípa:Ìpínlẹ̀ Anambra Ṣe Ìbáṣepọ̀ Pẹ̀lú Ilé Iṣé Tó Ń Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Nípa Iṣé

Ìjọba ìpínlẹ̀ náà ti dábàá wíwo ilé-èpò mẹ́tàlá tí wọ́n tí lugbadi òfin náà ní Ekwulobia, ní ìjọba ìbílẹ̀ Aguata ní ìpínlẹ̀ náà.

Ẹgbẹ́ náà tún halẹ̀ látí ríi gbogbo àwọn Ilé-èpò ìpínlẹ̀ náà tí ìjọba ìpínlẹ̀ náà bá kùnà láti sàn owó gbá mabinu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó bá kàn.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button