Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-ẹjọ́ Ṣé Ìdájọ Ìbàjẹ́ Ààrẹ Tẹ́lẹ̀ Tí Mauritania ‎

Lekan Orenuga

235

Ilé-ẹjọ́ kò-tẹ́-mí-lọ́run tí Ìlú Mauritania tí dájọ ẹ̀wọn ọdún mẹ́ẹ̀dógún fún Ààrẹ tẹ́lẹ̀, Mohamed Ould Abdel Aziz pẹ̀lú owó ìtanràn mílíọ̀nù mẹ́ta dọla ($3 million), ìdájọ́ yí fí ẹsẹ ìdájọ́ ọdún 2023 rínlẹ̀.

‎ O jẹ́ àgbà ológun tẹ́lẹ̀ kán tó fí ipá gbajọba gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ láti odún 2009 sí ọdún 2019, tí jẹ̀bi jíjẹ òwò ìlù lọnà tí kó tọ.

‎ Àwọn oniwadii sọ pé, o kó jú àádọ́rin mílíọ̀nù dọla ($70 million) láàrin àwọn ọjọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Ààrẹ Orílẹ̀-èdè náà. O wà ní atimọle láti ìgbà ìdájọ́ àkọ́kọ́ tí ọdún tó kọjá.

Comments are closed.

button