Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Ṣé Ìdádúró Àwọn Àjọṣepọ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Lókè Òkun Fún Ọdún Márún

Lekan Orenuga

201

Mínísítà fún ètò Ẹ̀kọ́, Dókítà Maruf Alausa, tí kéde ìdádúró ọdún márún lórí àjọṣepọ̀ ètò ẹ̀kọ́ lókè òkun látí ṣé ìdàgbàsókè àlàáfíà fún àwọn ọmọ Ilé-ìwé.

‎ Nígbàtí o n sọrọ lẹ́yìn àtúnyẹwò nlá tí àwọn ètò ẹ̀kọ́ ní àwọn ìlú òkèèrè, Dókítà Alausa sọ pé gbogbo ìmọ ẹ̀kọ́ tí àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè yìí ń lọ́ fún loke òkun, ló tí wà ní àwọn ilé-ìwé wá ní Orílẹ̀-ẹ̀dẹ̀ Nàìjíríà.

‎ Nígbàtí o n sàlàyé lórí ìpinnu náà nínú ọrọ tí Olùdarí Àwọn ìròyìn tí ilé-iṣẹ́ náà, Boriowo Folashade, Mínísítà náà tẹnumọ pé l’àkókò tí ìdádúró náà ṣé ìwúrí fún àwọn ilé-ẹ̀kọ́ tí orílẹ̀-èdè yìí, kó ṣé idiwọ fún àwọn obi láti ṣé àtìlẹ́yìn fún àwọn ọmọ wọ́n látí kàwé ní òkè òkun.

Comments are closed.

button