Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti gbóríyìn fún àwọn olùdíje nínú ìdíje eré ìdárayá gbogbogbòò ní Delta, Ọdún 2022.

0 278

Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, Seyi Makinde, ti ki àwọn ọmọ ẹgbẹ ti ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tó kópa nínú ìdíje eré ìdárayá gbogbogboo  ti yóò wáyé ni ìpinlẹ̀ Delta, Ọdún 2022., lóríi iṣẹ takuntakun tí wọn ṣe àti àṣeyọrí níbi ayẹyẹ náà.

Gómìnà gbóríyìn fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, ti o gbé igbá orókè nínú àwọn eré ìdárayá oríṣiríṣi, níbi ìparí ìdíje eré ìdárayá gbogbo ti Delta, Ọdún 2022 kọkànlá, àti fún gbígbé àwọn ami-ẹyẹ góòlù àádọta, fadaka mọ́kànléláàdọ̀ta àti idẹ mẹ́jìlélọ́gọ́ta, èyí tó sì mú wọn dé ipò kẹrin nínú ìdíje náà, wọn fi àmì méjì lè ti ọdún tó kọjá ní Edo 2021.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button