Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò Ìdìbò Ọdún 2023 Yóò Lọ Ní Ìrọwọ́-Rọsẹ̀- Olùdámọ̀ràn Lórí Ètò Àbò Fọwọ́ Sọ̀yà

0 293

Olùdámọ̀ràn sí Ààrẹ lórí ètò ààbò, Ọ̀gágun Ajagunfẹ̀yìntì Babagana Monguno ti fi àwọn ọmọ Nàìjíríà lọ́kàn balẹ̀ wípé ìdìbò àpapọ̀ ọdún 2023 yóò kẹ́ṣẹ járí.

 

Monguno fi àrídájú náà léde nígbà tí ó se ìpàdé pọ̀ pẹ̀lú àjọ elétò ìdìbò àti adarí àwọn ọmọ ogun orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

 

Ó gba àwọn ọmọ Nàìjíríà nímọ̀ràn láti má se tẹ̀lé ìsìdarí àti ìròyìn èké àtipé ìdìbò àpapọ̀ tí ó ń bọ̀ yóò lọ ní ìrọwọ́-rọsẹ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button