Abuja Metropolitan Management Agency (AMMC) sọ pé àwọn yóò ti tàbí fagilé àwọn ile itura tí ń ṣiṣẹ́ ní àwọn agbègbè ìbùgbé kànkan ní olú-ìlú Nàìjíríà, Abuja tí kò ní ìwé-àṣẹ, lẹ́yìn tí wọ́n ti fún wọn ní ìwé ìkìlọ̀ olọ́sẹ̀ méjì.
Alakoso Ìgbìmọ̀ náà, Tpl Umar Shuiabu lakoko ti o n ṣe afihan àwọn ìgbésẹ̀ tó fa kí wọn fagilé àwọn ilé-ìtura ìgbàlódé, awọn ile àlejò àti àwọn ilé ìtura abẹ́lé, laarin àwọn mìíràn ni Abuja (FCT), ni láti dènà àìsí ààbò tó péye ní olú-ìlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply