Àjọ EFCC Pàrọwà Sí Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Láti Jìnà Sí Ìwà Àjẹbánu Lójúná Àti Mú…
Àjọ EFCC ti pàrọwà sí àwọn akékọ̀ọ́ láti kó ipa tí ó làmì laaka lójúnà àti gbógunti ìwà àjẹbánu èyí tí ó sàfihàn irúfẹ́ ìgbésẹ̀ bẹ́ẹ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
…