Take a fresh look at your lifestyle.

Ìrìnàjò Hajj Ọdún 2025: Ìgbìmọ̀ Alálàájì Ìlú Abuja Ti Bẹ̀rẹ̀ Àyẹ̀wò Ìlera Fún Àwọn…

Ìgbìmọ̀ Alálàájì ẹka ti Abuja ti kéde ìbẹ̀rẹ̀ àyẹ̀wò ìlera fún àwọn tí ó ń gbèrò láti rin ìrìnàjò lọ sí ilẹ̀ mímọ́ Saudi Arabia ní ọdún 2025   Nínú ọ̀rò kan tí ó fi léde láti ẹnu olùfọ̀rọ̀léde àjọ…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti Saudi Arabia Gbé Ìgbésẹ̀ Akin Láti Gbógunti Gbígbé Òògùn…

Àjọ NDLEA àti ojúgbà rẹ̀ ti Orílẹ̀-èdè Saudi Arabia, GDNC ti buwọ́lu ìwé àdéhùn pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láti gbógunti gbígbé òògùn olóró àti àsìlò òògùn   Lára àdéhùn àjọ méjéèjì náà ní…

Mínísítà Ètò Ìròyìn Kó Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ Sòdí Láti Kópa Nínú Àpérò Ìfọ̀rọ̀léde…

Mínísítà Ètò Ìròyìn Àti Ìlanilọ́yẹ̀, Alhaji Mohammed Idris ti kọ́wọ̀ọ́rì pẹ̀lú awọ̀n asojú ìjọba ní ẹka ìròyìn lọ sí ibi àpérò àti ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn oníròyìn ti ọdún 2025, èyí tí ó wáyé ní Las…

Ẹ Jìnà Sí Ìròyìn Òfegé Fún Ìdàgbàsókè Àwùjọ- Alákòso Ilé Iṣẹ́ Ìròyín Ìpínlẹ̀…

Alákòso Ilé Iṣẹ́ Ìròyìn ti Ìpínlẹ̀ Ebonyi, Ọ̀gbẹ́ni Tony Nwizi ti pàrọwà sí àwọn oníròyìn láti tẹ̀síwájú nínú ojúse rere nínú iṣẹ́ wọn, àti láti máa tẹ́ pẹpẹ àwọn àseyọrí ìjọba ní gbogbo ìgbà fún…
button