Ó Di Dandan Kí Ìtàjẹ̀sílẹ̀ Dópin Ní Ìpínlẹ̀ Plateau- David Mark Pàrọwà Sí Ìjọba Àpapọ̀
Ààrẹ Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin tẹ́lẹ̀rí, sẹ́nétọ̀ David Mark ti pàrọwà sí Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu láti se àtúntò àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò lójúnà àti wá ojútùú sí àìrajaja ètò ààbò irúfẹ́ èyí tí ó ń wáyé ní…