Take a fresh look at your lifestyle.

Sẹ́nétọ̀ Ewuga Àti Àwọn Ènìyàn Pàtàkì Míràn Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Òsèlú APC Ní Ìpínlẹ̀…

Alága àpapọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú APC Alhaji Abdullahi Ganduje ti tẹ́wọ́gba mínísítà kejì tẹ́lẹ̀rí fún olú ìlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sẹ́nètọ̀ Solomon Ewuga àti àwọn ènìyàn pàtàkì míràn sí inú ẹgbẹ́ òsèlú APC…

Gbèdéke Àmúse Iṣẹ́ Se Pàtàkì Fún Àjọ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Lójúnà Àti Pèsè Àbò Tí Ó…

Àjọ alẹ́nulọ́rọ̀ kan ti pàrọwa ̀sí Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu láti fún àjọ ẹ̀ṣọ́ aláàbò ní gbèdéke osù mẹ́fa láti mú ìyípadà bá ètò àbò kí wọ́n sì wá ojútùú sí gbogbo wàhálà èyí tí ó ń wáyé ní…

Ìgbésẹ̀ Ìjọba Àpapọ̀ Láti San Ìdajì Nínú Owó Orí Ọkọ̀ Lásìkò Ọdún Tuntun Kò So Èso…

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìjọba àpapọ̀ san ìdajì nínu owó ọkọ̀ lásìkò ọdún tuntun, àwọn awọkọ̀ fi ẹ̀dùn ọkaǹ hàn pé níse ní owó ọkọ̀ tún gbówó lórí ju bí ó ti se yẹ lọ À̀àrẹ Tinubu kéde ìrànwọ́ lórí…

Àrọwà Ti Wá Fún Ọmọ Nàìjíríà Láti Siṣẹ́ Takun-takun Fún Ìsàgbékalẹ̀ Ètò Ọrọ̀ Ajé…

Alága Àti Olùdásílẹ̀ Ilé Iṣẹ́ Funab, Alhaji Ibrahim Mohammed Ajia ti késí gbogbo ọmọ Nàìjíríà láti fi ọwọ́ sowọ́pọ̀ fún ìsàgbékalẹ̀ ètò ọrọ̀ ajé tí ó yè kooro èyí tí yóò mú ìdàgbàsókè bá Orílẹ̀-èdè…
button