Ìjoba Àpapọ̀ Pàrowà Sí Àwọn Adarí Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Láti kópa Nínú Ìmúgbòòrò Bá Ètò…
Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kashim Shettima ti pàrọwà sí àwọn adarí ilẹ̀ adúláwọ̀ láti kópa tí ó yanjú lójúnà àti mú ìdàgbàsókè bá ètò ọrọ̀ ajé àgbáyé
Igbákejì ààrẹ, Shettima…