Àwọn Ènìyàn Ìpínlẹ̀ Èkó Fi Ariwo Ta Látàŕi Òògùn Ìdáàbò Bò Lásìkò Ìbálòpọ̀…
Àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Èkò ti ké gbàjarè látàrí òògùn ìdáàbò bò tí ó gbówó lórí èyí tí ó le è fa ìtànkálẹ̀ àrùn àti àìrò-tẹ́lẹ̀ oyún
Níbi ìfọ̀rọ̀-wáni-lẹ́nu -wò tí ó wáyé ní àwọn…