Igbákejì Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Sèdárò Lẹ́yìn Ikú Olóògbé Wigwe
Igbákejì Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin, Benjamin Okezie Kalu fi ẹ̀dùn ọkàn hàn látàrí ìpapòdà olùdarí Ilé Ìfowópamọ́ Aceess, Ọ̀gbẹ́ni Herbert Wigwe, ìyàwó àti ọmọkùnrin rẹ̀ nínú ìjàm̀bá ọkọ̀ òfurufú ní…