Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Aláàánú Ọmọnìyàn Kan Fí Ohun Amáyédẹrùn Ta Ọgbà Ìsàtúnṣe Ọmọnìyàn Lọ́rẹ

Àjọ aláàánuh ọmọnìyàn ti Emeka Offor fi ẹgbẹ̀rún àpò ìrẹsì, ẹgbẹ̀rún, àpò ẹ̀wà àti àwọn oúnjẹ míràn ta ọgbà ìsàtúnṣe ọmọnìyàn lọ́rẹ ní òpin ọ̀sẹ̀, ní ìpínlẹ̀ Anambra   Alákòóso ọgbà ìsàtúnse…

Pope Pàrọwà Sí Àwọn Tí Ọ̀rọ̀ Kàn Láti Fi Òpin Sí Ogun Abẹ́lé Orílẹ̀-èdè Sudan

Pope Francis pàrọwà ní ọjọ́ Àìkú sí àwọn ikọ̀ méjéèjì tí ọ̀rọ̀ kàn láti fi òpin sí aáwọ̀ tí ó ń wáyé láti osù mẹ́wàá sẹ́yìn, níbi tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ti fi ibùgbé wọn sílẹ̀   Ó sàfirinlẹ̀ àrọwà…

Ẹ gba Àwọn Ọmọ Níyànjú Láti Lọ Sí Ilé Ẹ̀Kọ́ – Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kano Gba Àwọn Òbí…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano, ẹkùn ìwọ̀ oòrùn Àréwá Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti pàrọwà sí àwọn òbí, ní papàá jùlọ àwọn ìyá, láti rí i dájú pé àwọn ọmọ lọ sí ilé ẹ̀kọ́, èyí tí yóò sé ìgbélárugẹ fún ètò…

Ẹ̀kọ́ Tí Ó Yè Kooro Se Pàtàkì Fún Àwọn Ọmọdébìrin- Olurẹmi Tinubu

Aya Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Olurẹmi Tinubu ti darapọ̀ mọ́ àwọn ojúgbà rẹ̀ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ láti se àmójútó ẹ̀kọ́ àwọn ọmọbìnrin kí wọ́n le è figa-gbága pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ́ wọn lọ́kùnrin   Ó sàlàyé pé…
button