Take a fresh look at your lifestyle.

Tinúbú Yóò Se Isẹ́ Pọ̀ Pẹ̀lú Ẹ̀yà Ìwọ̀ Oòrùn Àríwá Fún Ìtẹ̀síwájú

Ìyàwó Oludije Ipò Ààrẹ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), Sénétọ̀ Olúrẹ̀mí Tinúbú ti ṣèlérí pé ọkọ òun yóò ṣe iṣẹ́ pọ̀ pẹlú ẹ̀yà Ìwọ̀ Oòrùn Àríwá, yóò ṣì tún bá àìní wọn pàdé tí wọ́n bá yàn án sí ipò ààrẹ ní ọdún 2023.…

Sénétọ̀ Ekwunife Sọ Fún Àwọn Olùdìbò Láti Wo Isẹ́ Tí Àwọn Olùdíje Ti Ṣe Sẹ́yìn Kí Wọ́n Tó Yàn Wọ́n…

Sénétọ̀ tó ń sojú agbègbè Àárín gbungybun Ìpínlè Anambra, Sénétọ̀ Uche Ekwunife ti pe ìpè fún àwọn olùdìbò láti ríi pé àkọsílẹ̀ ati iṣẹ ti àwọn olóṣèlú tó ń darí lọ́wọ́ ni wón lò láti tún yan àwọn akẹgbẹ́ wọn tuntun míràn sí ipò…

Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè South Africa Se Ìwọ́de Láti Tako Ìdásílẹ̀ Apànìyàn Ẹlẹ́yàmẹyà Kan

Aláatìlẹyìn ẹgbẹ́ olùṣàkóso ti South African, ANC àti ẹgbẹ́ South Africa’s Communist Party ti se Ìwọ́de ní ìta ilé ẹjọ́ ti òfin ní ìlú Johannesburg. Àwọn olùwọ́de náà wọ́de láti tako ìdásílẹ̀ olùtakò ajààngbara ẹlẹ́yàmẹyà Chris Hani, tí…

Ẹni Tó Ní Ilégbèé Kan Ní Orílẹ̀ Èdè Kenya Tó Dáwọ Lulẹ̀ Yóò Kojú Ẹ̀sùn

Àwọn alákóso Ọlọ́pàá ní Orílè-èdè Kenya ti sọ pé ẹni tó ní ilé alájà máàrún tó dàwó lulẹ̀ ní ọ̀ṣẹ̀ tó kọjá ní agbègbè Nairobi yóò kojú ẹ̀sùn Ìpànìyàn Ilé náà lulẹ̀ sórí ilé tó sún mọ́ọ tó sì pa ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn. Olópàá sọ pé wọ́n…
button