Ẹgbẹ́ Àwọn Òṣèré Se Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Ọmọ Ẹgbẹ́ Wọn Tó Gbégbá Ìbò
Àwọn ọ̀gá nínú ẹgbẹ́ àwọn òṣeré - Actors Guild of Nigeria, AGN ti orílẹ̀-èdè yíi ti rọ̀ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ jákèjádò ilẹ̀ yìí láti súgbàá, se àtìlẹ́yìn, diìibò fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tí wọ́n gbégbá Ìbò.
Ààrẹ ẹgbẹ́ AGN, Emeka Rollas sọ…